Oriki Ibeji

Twins

Play
Pause

Yoruba

Winíwíní lójú orogún Ejiwọ̀rọ̀ lojú ìyá è̟, Ejirẹ́ ará isokún, Edúnjọbí, Ọmọ a gbórí igi réferéfe, Ọkàn ń bá bí, éjì ló wọlé tọmíwá, Obẹ́kişi bẹ́kẹ́ṣẹ́, Ó bẹ́ sílé alákísa, Ó salákisà donígba aşọ. Gbajúmo ọmọ tíí gbàkúnlè ìyá, tíi gbàdọ̀bálẹ̀ lówọ́ baba tó bí í lọmọ Bi Táyélolú ti nlọ niwájú, Bẹẹni, Kehinde ń tẹle èe, Táyélolú ni àbúrò, Kehinde ni ẹ̀gbọ́n, Táyélolú ni a rán pé kí o lọ tọ́ ayé wò, Bile ayé dára, bi ko dára O tộ ayé wò, Ayé dun bi oyin Táyélolú, Kehinde, ni mo ki Ejiwòrò lojú ìyá ẹ O dé ilé ọba tẹ̀rín-tẹ̀rín, ó de’le ìjòyè tọyayatọyaya Jẹ́ kí nrí ję, kí n rí mú, Orí mí jé ń bí ìbejì l’ọ́mọ Ọba ọmọ ni wọ́n!

English

Every Twins hail from Isokun.
A relative of the Columbus monkeys you are
Hoping and jumping from a tree branch to the other
Jumping helter-skelter, you landed in a wretched man’s place
Turning around his misfortunes into great fortune
A rare set of children that commands undue honour and respect from their parents
To your stepmother, you are an unwelcome sight
But to your mother, you are both emperors of two empires
You are the king of children!

Open chat
1
Scan the code
Powered by Beyondculturewba
Hello 👋
Contact Us for Oriki enquiries